LYRICS
Ìyìn yẹ ó
Ọba tó fẹ́mi
Ògo yẹ ọ
Ọba tó fẹ́mi
Kábíèsí rẹ ò
Ìyìn yẹ ó
Ọba tó fẹ́mi
Ògo yẹ ó
Ọba tó fẹ́mi
Kábíèsì rẹ ò eh
Ìyìn yẹ lére rẹ Ọba tó fẹ́mi (ìyìn yẹ Ọ Ọba tó fẹ́ èmi)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (Ògo yẹ Ọba tó fẹ́ èmi)
Kábíèsí rẹ ò (oooo)
Ìyìn yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (fún Olú Ọ̀run)
Ògo yẹ ọ Ọba tó fẹ́mi (Ọba tó da sími)
Kábíèsí rẹ ò e
Instrumentals
Ó gbà mí lọ́wọ́ ikú
Ọ̀rẹ́ mi òtitọ́
Ó fi kẹ́kẹ́ ogun ayé mi jóná
Olú gbèjà mi ni
Kò sẹ́ni tó lè ṣé o; àfìwọ
Kábíèsí rẹ e
Mo júbà mo forí balẹ̀ f’Ọ́ba
Ìwọ ni ológo jùlọ̀
Ìyìn yẹ lére rẹ Ọba tó fẹ́mi (ìyìn yẹ ilé rẹ Bàbá)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (Ọlá ògo to ń gbé orí ìtẹ́ pàṣẹ)
Kábíèsí rẹ o (o pàṣẹ ìyìn ọ̀rọ̀ fún aye mi o ṣé)
Ìyìn yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (ìyìn yẹ Ọ ooo)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (Ògo yẹ Ọ ooo)
Kábíèsí rẹ o e
Ó fọ́ gbogbo ìlẹ̀kún idẹ àbá wọlé sí ògo mi
Ó jó gbogbo jànkáríwò
Ẹ̀mí òdì wọ́n tẹ́ríba
Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀
Wádi pàtàkì igun ayé
Ọwọ́ àanú rẹ̀ tó fi gbà mì, óga
Mo ṣèbà fẹ́lẹ́yinjú ìfẹ́ o
(Ìyìn yẹ Ọ o) Ìyìn yẹ lé rẹ Ọba tó fẹ́mi (mó gbé Ọ ga Bàbá)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (àrà tó fayé mi dá hehe)
Kábíèsí rẹ o (O jọmí lójú)
(kábíèsí rẹ o) Ìyìn yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (kábíyèsí rẹ o)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (Ògo yẹ Ọ o)
Kábíèsí rẹ o e
Instrumentals
Ọ̀na mí là mo ri ore ọ̀fẹ́
Látọ̀dọ̀ Aṣẹ̀dá
Ọwọ́ olóńdè gé sọnù
Ohun ìjà wọn ló nù lọ́rọ̀
Èmi lẹ̀rí èmi lògo
Àsọtẹ́lẹ̀ ni mo jẹ́ o
Májẹ̀mú Ọlọ́run ń fọhùn láyé mi
Mo fìyìn fá dúró ti ni gbágbá
Èmi lẹni tí Olúwa fẹ́ gan an
Tí asì dá láre o hehehe (ẹni tí Olúwa fé)
Ìyìn yẹ lére Ọba tó fẹ́mi (a dámiláre, a ṣemi lógo)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (a baṣọ ìyìn wọ̀ mí o Ọlọ́run)
Kábíèsí rẹ o (kábíyèsí rẹ)
Ìyìn yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (o mú mi jókò láàrin àwọn ọmọ ọba láyé)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mí (Ó sọ mí d’oba)
Kábíèsí rẹ e
Ìyìn yẹ lé rẹ Ọba tó fẹ́mi (ìyìn yẹ ọ, o yẹ ọ)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (Ìwọ ni maa fi gbogbo ayé mi sìn)
Kábíèsí rẹ o (Kábíèsí rẹ baba)
Ìyìn yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (ìyìn yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi)
Ògo yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi (ìyìn yẹ Ọ Ọba tó fẹ́mi)
Kábíèsí rẹ o e
_____