LYRICS
Eni à ba ta k’a fi r’atupa ni mi
Ajitannnawo ti mo da ope l’o ye’Lu
O to mi s’ona t’o ye n gba t’Oba l’ope
Ade O de mi mo gbe kale niwaju Re
Mo te’ri okan mi ba o s’Olorun mi
Repeat
Ajitananwo ti mo da – Ope mo mu wa
Ajitannawo ti mo da – Ope mo mu wa
Irugasoke ko rara – Mo s’ope f’Olu
Anu mo ri gba – emi ko o ope
Irugasoke ko rara mo s’ope f’Olu
Aanu mo ri gba emi ko ope
Iboju ya ewon bo eru mi fuye
Ile oro ti mo wo ope
Eni à bá tà ka fi r’àtùpà, etc.
2. Ago igbala ni mo gbe ope
Maa polongo oro yi titi
Kos’ohun to wa ti Baba ò le tan
Eni wa l’eyin ogba yara wole
Iboju á ya ewon á bo eru re a fuye o
Ago igbala l’emi gba ope!
Eni à bá tà k’a fi r’atupa, etc
Ajitannawo ti mo da – Ope
Ajitannawo ti mo da – Ope
Aanu Oluwa lo gba mi o – Ope
Ko jo pe bayi laa ri o – Ope
Yiyo Eleda ni mo ri o – Ope
Fun gbogbo anfani ati iranwo ti mo n ri lo – Ope
Aanu po l’odo Baba wa – Wa
Eni wa l’eyin ogba wole wa o – Wa
Iwo naa wa o si wa – Wole
Iwo naa wa yara maa bo – Wole
Irira t’o bà sori ogo – A tan
Idamu t’o wa lori ogo – A tan
Iwenu a sele omo o – Waa bo
Okun a ja, ewon a bo, iboju a ya
Iri a se s’ori ogo – Itura a de
Imuse a wa itura a wa – Itura a de
Ajitannawo ti mo da – Ope
Ago igbala ti mo gba – Ope
_____