LYRICS
Ẹ̀ mà bámi ki ooo
Ẹ̀ mà bámi ki aaaa
Ọba tóṣe mi lóore
Ẹ̀ mà bámi ki ooo
Ẹ̀ mà bámi ki aaaa
Oba t’óṣe mi láanú o
(Instrument)
Ẹ̀ mà bámi ki ooo
Ẹ̀ mà bámi ki aaaa
Ọba tóṣe mi lóore eee
Ẹ̀ mà bámi ki ooo
Ẹ̀ mà bámi ki aaaa
Ọba t’óṣe mi láanú o
(Ẹ mà baan ki)
Ẹ̀ mà bámi ki ooo (E ma bami ki o)
Ẹ̀ mà bámi ki aaaa
Ọba tóṣe mi lóore (Ọba tóṣe mi lóore)
Ẹ̀ mà bámi ki ooo
Ẹ̀ mà bámi ki aaaa
Ọba t’óṣe mi láanú o (Ọba t’óṣe mi láanú o)
I know I don’t deserve the love you show to me
Kíni molè fi san o
À f’ọpẹ eeee
Ó ṣètò aye mi dáradára o
Ó fi mí dárà ire
Ọ̀nà àrà l’ógbà, óyẹ kín ki
Oh what kind of faithfulness is this, O Lord
Ó jẹ olódodo sími tinú tẹ̀yìn o
Olóre mi alánu mi
Tí kì ṣú o
Mo ma dúpẹ ore am grateful o
Ẹ̀ mà bámi ki ooo
Ẹ̀ mà bámi ki aaaa (mo wá dúpẹ́ ore ni)
Ọba t’óṣe mi l’ore (èrò ẹ ba n ki, ẹ ba n ki)
Ẹ mà bámi ki ooo
Ẹ mà bámi ki aaaa
Ọ̀ba t’óṣe mi láanú o (Ọ̀ba tó wò mí sùnsùn ṣemí láanú)
Your mercy is what am dwelling into Since I was in my mother’s womb
Olúbí tó ṣẹ̀dá to fẹsẹ̀ mi lélẹ̀
You have been my shield my shelter and light
Ìwọ lotó mi bò o
Páńpẹ ọ̀nà ayé kòjẹ́ kó mú mi
Morìn láfònifojì kòtò gegere o ṣọ́ mi
Your bound with me is love
Olùṣọ́ ẹ̀mí àti ayé tí mo ní
A kẹ́ni A gẹni n o ròyìn rẹ fáráyé kọ́n ba n kí Ọ
(Kọ́n ba n kí Ọ)
Ẹ̀ mà bámi ki ooo (Ó ṣemi lóre)
Ẹ̀ mà bámi ki aaa (Ó gbà mí là)
Ọ̀bà t’óṣe mí l’ore (Ooo pọ̀ lójú mi e)
Ẹ̀ mà bámi ki ooo (O kọjá òye mi)
Ẹ̀ mà bámi ki aaaa (Ẹ ba n ki)
Ọ̀bà t’óṣe mí làanú o (ẹ ba n ki o)
Bótiwù k’ógun pọ̀tó
Bótiwù kọ́tà pọ̀tó
Ọlọ́run jẹ́ olódodo o
Bówu ọ̀sà kó masá
Bówu òkun kó ma kùn
Òdòdo Ọlọ́run yóò wà títí láe
Bótiwù kọ́nà jìn tó
Bótiwù kó kẹ́da tó
Ọlọ́run jẹ́ olódodo o
Bótiwù kẹ́kún potó
Bótiwù kẹ́rin pọtó
Òdòdo rẹ Ọlọ́run yóò wà títí láe
Ó jẹ́ olódodo
Òdòdo rẹ̀ kòmà lópin
Ó jẹ́ olótitọ́
Kìma i ṣèké bí ènìyàn o
Ọ̀rọ̀ tóbá tẹnu rẹ̀ jáde òdòdo ni
Ó gbé ọ̀rọ̀ rẹ̀ ga ju orúkọ ara rẹ̀ lọ o
Ẹ mà bámí ki ooo (Ẹ̀ mà bá n ki)
Ẹ mà bámí ki aaa (Ẹ̀ mà bá n ki)
Ọ̀ba t’óṣe mi l’ore (Aláanú olóore ọ̀fẹ́ mi)
Ẹ mà bámí ki ooo (Ẹ̀ mà bá n ki o)
Ẹ mà bámí ki aaa (Ẹ̀ mà bá n ki Olorun)
Ọ̀ba t’óṣe mi láanú o (Ó ṣeun Ó ṣeun)
Ẹ mà bámí ki ooo (Ẹ̀ mà bá n ki)
Ẹ mà bámí ki aaa
Ọ̀ba t’óṣe mi l’ore (Olúwa mi)
(Ọlọ́run mi)
Ẹ mà bámí ki ooo (Ha kẹ́mi)
Ẹ mà bámí ki aaaa (Ó ṣeun)
Ọ̀ba t’óṣe mi láanú o (O ṣeun, mo dúpẹ́ ore o)
Kòsí lákọjá tí o mọ̀
Ìjì ń jà lóko Jésù sún ororí
Ọjọ́ gbó lórí Sárà
Pẹ̀línà ń fi Hánà ṣẹ̀rín rín
Bótiwù kọ́jọ́ pẹ́tó Kéníyàn gbàgbé ẹ tó
Látinú agbo ẹran
A mú Dáfídì kekere
Kó wá jọba
Ó jẹ́ olódodo
Òdodo rẹ̀ kòmà lópin
Ó jẹ olótitọ́ ki máìṣe ènìyàn
Kólè gbàgbé láe
Ọ̀rọ̀ tóbá tẹnu ẹ̀ jáde
Òdodo ni, o gbé ọ̀rọ̀ rẹ̀ ga jú orúkọ ara rẹ̀ lọ
Ẹ mà bámí ki ooo (Ẹ ba n ki)
Ẹ mà bámí ki aaa (Ẹ ba n ki)
Ọba tóṣe mi lóre (ògo aye ẹ parapọ̀ wa bá mi gbe ga)
Ẹ mà bámí ki ooo (E ba n ki)
Ẹ mà bámí ki aaaa (E bami gbe ga o)
Ọba tóṣe mi láanu o (hunhunhun)
Ẹ mà bámí ki ooo (E ba mi ki)
Ẹ mà bámí ki aaa (E bami gbe ga)
Ọba tóṣe mi lóre (Ọlọ́wọ́ gbọgbọọrọ tó yọmi lọ́fin lọ́fin o)
Ẹ mà bámí ki ooo (Aláanú mi)
Ẹ mà bámí ki aaaa (Alaabo lori ebi mi)
Ọba tóṣe mi láanu o (Ọba tóṣe mi láanu)
Ẹ mà bámí ki ooo (Ẹ ba mi ki)
Ẹ mà bámí ki aaa (I don’t know what to say again)
Ọba tóṣe mi lóre (I just want to say thank you)
(I just have to bless your name)
Ẹ mà bámí ki ooo (I lift you up my Lord)
Ẹ mà bámí ki aaaa (I magnify your holy name)
Ọba tóṣe mi láanu o (Oba tose mi lanu o)
_____