LYRICS

I have Jesus there’s no fear
He lives right inside of me
I’m more than conquerors
Because my Redeemer lives
No more worries for me
No pain, No lost but Gain
In his assurance I stand
I see my future brighter
Jesus the song of strength I sing
No more worries for me
Ẹ gbọ́ orin ayọ̀ lẹ́nu mi
In his assurance I stand
Onílé ayọ̀ ti tún mi ṣe
Jesus the song of strength I si-ing
Jesus the song of Strength I sing
He brought me out from mariclay
Set my feet on the solid rock
Songs of praise shall never seize
Lẹ́nu mi oo títí láe
Holy ghost songs of power I si-ing
Holy ghost songs of power I sing
Holy ghost songs of power I sing
Holy ghost songs of power I sing
I have been far away
In his arms he prompt me home
Closed my heart locked all doors
He kept no key till I open
Now am redeemed of the Lord
Ẹ wò mí o ooo
Jesus the song of salvation I sing

Chrous: No More worries for me
(Kòsí ìbẹ̀rù o)
Ẹ gbọ́ orín ayọ̀ lẹ́nu mi
(Kòsí ìdàmú, kòsí yílàyìlo fún mi o)
In his assurance I stand
(Ẹ̀mí mímọ́, sọmí dọ̀tun)
Oníṣẹ́ àrà sọ mí dọ̀tun (Ee aaaaa)
No more worries for me (Mo ní kòsí ‘bẹ̀rù o)
Ẹ gbọ́ orín ayọ̀ lẹ́nu mi (Bẹni kòsí fàkàfiki)
In his assurance I stand
(Kòsí yílàyilo, ọkàn mi kò gbé sọ ke e)
Oníṣẹ́ àrà sọ mí dọ̀tun
(Ọlọ́run ló jẹ́ kó tù mí ooo)
Jesus the song of strength I sing
(Ìwọ ni, Ìwọ lorin agbára mi ooo)
Jesus the song of strength I sing
(Ìwọ lorin, tí mo un kọ o)
Ẹ wá bá mi yọ̀, mo ṣoríre
Ìgbàlà mi dọ̀tun, Halleluyah
Kòsí bẹ̀rù mọ́, by the blood of the lamb
Ati ṣẹ́gun fún mi
(Ẹ wá ba mi yọ̀ o, ati ṣẹ́gun fún mi o)
Ẹ wá bámi yọ̀ (Ẹ wá bámi yọ̀)
Mo ṣoríre
(Ee mo ṣo ríre)
Ìgbàlà mí dọ̀tun
(Ó dọ̀tun po)
halleluyah
(Alágbara gíga)
Kòsí ‘bẹ̀rù mọ́
(Ọ̀gangan ojú áńgẹ́lì lóṣe mi l’óre)
By the blood of the lamb
(Eee)
Ati ṣẹ́gun fún mi
(Nípa ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ̀ àgùntan ooooo)

No matter what have been through
Christ set me free, free indeed
About the song of victory I sing
Rescue not captive again
Gotten inheritance of heaven
My life filled with testimonies
His love overshadows me
Oo my fear already gone
Mo ríre gbà lọ́wọ́ aṣẹ̀dà oo
Praise is the gratitude I bri-ing
Orin ìyìn lọpẹ́ ẹ tí mo mú wá
Mo gbé gbá ọpẹ́ mi de o
Atáyé rọ ma tórí mi ṣe oooo
Orin ìyìn lọpẹ́ ẹ tí mo mú wá (Orin ìyìn lọpẹ́ ẹ tí mo mú wá)
Ará ẹ bá mi dúpẹ́
Mo ranú gbà ará dẹmi gbẹ̀dẹ̀ o
Praise the gratitude I bring
(Ọpẹ́ rànbẹ̀dẹ̀ ni mo gbé dé o)
(O ṣe olú, o ṣe olú)
I’m a barrier breaker
Aládé ògo ló Lànà fémi
Orin ìyìn lọpẹ́ ẹ tí mo mú wá
(A orin ìyìn lọpẹ́ ẹẹ, tí mo mú wá, tí mo mú wá)
Ìtàná ìpàdó mi, ẹni tó tan ìmọ́lẹ̀ fayé mi mọ̀ nà o

Praise is the gratitude I bring
Mo wa dẹ̀rí, mo dògo
Èmi làsọtẹ́lẹ̀, olú lóṣe mí bẹ̀ e
N ó ma sìn yín títí
Orin ìyìn lọpẹ́ ẹ tí mo mú wá
Gbogbo ìdè mi ló já pátápátá
Atú mí sílẹ̀, èmi mà yege ooooo
Praise is the gratitude I bring (n o kọ ọ lórin)
Orin ìyìn lọpẹ́ (n o ka o le wo)
Praise is the gratitude (n o sọ o lọ́rọ̀)
Praise is the gratitude (àkàndá lè mi)
Orin ìyìn lọpẹ́ e
(Èmi ni ẹni ti a ṣànu fún, èmi lẹni nà tí a dá láre)
Tí mo mú wá

TRANSLATION


Added by

admin

SHARE

WRITE A TRANSLATION OR SUGGEST CORRECTION FOR THIS LYRICS

ADVERTISEMENT