LYRICS

Èmi mo oun ojú mi ti rí
Mo mọ oun etí mi ti gbọ́
Mo oun ojú mi ti rí
Mo mọ oun etí mi ti gbọ́
Lọ́gán tó gbọ́ ìró ayọ̀ rẹ ò Olùgbàlà
Aiyé mi létò
Lọ́gán tó gbọ́ ìró ayọ̀ rẹ ò Olùgbàlà
Aiyé mi létò
Mo mọ oun aiyé mà ti wí
Mo mọ oun èèyàn mà ti sọ
Wọ́n ti pè wá ní àgàn rí
Bóyá wọ́n ti pè wá l’ólòṣì rí
Ṣùgbọ́n, lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà, layé mi létò
Ṣùgbọ́n, lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà, ayé ẹ létò.

Ayé tó ti dàrú tẹ́lẹ̀ tẹ́lẹ̀ o
Lọ́gán tí ó dé
Ọ̀rọ̀ tí ènìyán ti fi s’àlùfàní rẹ
Lọ́gán tí ó dé
Ọ̀rọ̀ tí kò dára ta ti sọ sí ọ
Lọ́gán tí ó dé
Orúkọ tí kìn ṣe tìrẹ ta ti pè ọ
Lọ́gán tí ó dé
Àní lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà ayé ẹ létò
Lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà,
ayé ẹ létò
Lọ́gán tí Jésù dé o Olùgbàlà,
l’ayé ẹ létò

Kò s’órúkọ t’áyé ò lè pe ni
Wọn á máa pe ni l’ágàn l’ọ́nà gbogbo
Bóò bá lówó lọ́wọ́ àgàn ni,
Bóò bá bímọ o àgàn ni.
Bóò bá tẹ́gbẹ́ ko dàgbà àgàn ló jẹ́
Ṣùgbọ́n lọ́gán tí ó dé,
Sọpé lọ́gán tí ó dé
Àní lọ́gán tí ó dé, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀,
Lọ́gán tí ó dé
Àní, lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà,
L’ayé ẹ̀ létò
Lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà,
L’ayé ẹ létò

Instantly ló ń jẹ́ bẹ́ẹ̀
Bó ṣe ń dé bayìí
Wọ́n dẹ̀ yí orúkọ padà
Lọ́gán tí ó dé, eh eh eh lọ́gán tí ó dé
Ẹni táa pè l’ágàn ẹ máa sọ wípé,
Lọ́gán tí ó dé
Àwọn ta ti f’orúkọ abúrú pè ní’lẹ̀ wọ̀nyí
Lọ́gán tí ó dé
Àní lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà, l’ayé mi létò
Lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà,
L’ayé mi létò
Ani eheh, lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà,
L’ayé mi létò
Àní, lọ́gán tí ó dé o aṣẹ̀dá,
L’ayé mi létò
Àní, lọ́gán tí ó dé o Ọlọ́run ò,
L’ayé mi létò
Ìràwọ̀ òwúrọ̀ ọmọ Mary yọ sínú ọ̀rọ̀ mi, l’ayé mi létò
Ah, alágbára ní Shiloh lóbá rántí mi sí rere, l’ayé mi létò
Ẹnu mi wá kún fún ẹ̀rín o gbogbo, l’ayé mi létò
Ayé mi gba ìyípadà ọ̀tun ò lọ́gán tó dé, l’ayé mi létò
Ayé mi bá létò l’ọ̀tá bá n wo ìran mi, l’ayé mi létò
Ayé mi létò ló ta bá ń wọ ìran mi, l’ayé mi létò
Ọ̀tá káwọ́rọ̀, ẹnu wọn gbẹ tán lórí ojú kan, l’ayé mi létò
Ahah, lọ́gán tí ó dé o Olùgbàlà, l’ayé mi létò
Thank you Lord Jesus for all that you are

TRANSLATION

I know what my eyes have seen
I know the things my ears have heard
I know what my eyes have seen
I know the things my ears have heard
But the moment I heard your good news, oh savior
My life found new meaning
But the moment I heard your good news, oh savior
My life found new meaning
I have heard the terrible gossip about me
I know what people must have said
There was a time they called us barren
Or perhaps, they once called you a failure
But the moment the saviour steps in, your life finds new meaning
But know this, the moment He arrives your life is set in order.

Your life may have been in chaos
But he shows up and instantly
Words may have been used against you
But he shows up and instantly
Terrible words may have been spoken over you
But he shows up and instantly
Even those unspeakable names that you have been called
But he shows up and instantly
I say the moment the saviour steps in, your life becomes meaningful
The moment the saviour steps in,
your life is set in order
The moment Jesus comes
into your life, your life is settled.

Men may call you all sorts of names
They may call you barren in many ways
If you don’t have money, you’re barren
When you don’t have children, you’re barren
If you are behind your peers they may call you barren
But he shows up and instantly,
Say after me: the moment he arrives
The moment he arrives, instantly,
the moment he steps in
The moment he steps in, the saviour
Your life becomes meaningful
The moment he steps in, the saviour,
your life is set in order

Logan means Instantly
As soon as he shows up,
he changes your name completely
The moment He arrives, ehehh, The moment He arrives
You who have been called barren, please say,
The moment He arrives
All those who have been terribly spoken about in this land
The moment He arrives
I say, the moment the saviour arrives, my life is transformed
The moment the saviour steps in, my life is settled
The moment the saviour steps in,
my life is set in order
I said eh eh The moment the creator steps in,
my life is transformed
I say, the moment he arrives, the creator
my life becomes meaningful
I said the moment he arrives, oh God,
My life becomes meaningful.
The morning star, born of Mary addressed my situation, my life becomes meaningful
The almighty one at shiloh who has remembered me for good, my life is settled
Now my mouth is filled with glorious testimonies, my life is transformed
My life has turned around for good the moment he stepped in, my life becomes meaningful
My life became an object of envy to my enemies, my life is set in order
My life became an object of envy to my enemies, my life is transformed
The enemies became totally helpless and surprised at what the saviour has done,
my life become meaningful.
The moment the saviour stepped in, my life becomes meaningful.
Thank you Lord Jesus for all that you are…

Added by

admin

SHARE

WRITE A TRANSLATION OR SUGGEST CORRECTION FOR THIS LYRICS

ADVERTISEMENT

VIDEO