LYRICS

Mimo ni O mimo ni O o mimo
Mimo ni O mimo ni O o mimo

Ad lib: Oluwa Olorun Eledumare t’O pò n’ipa ati agbara
Gbogbo iseda nso bee emi naa mo so bee
Lat’ogbun emi i mi

Mo juba Re Oba mimo
Mo wole fun Oba toto
L’eyin Re, ko si o
Iwo nikan ni Oba
(Repeat)

Ad lib: Awamaridi Oluwa
Iwo t’O wa n’ipekun imole, Iwo ni ekun ola, ekun ogbon, ekun agabara
Oba t’Ó joko s’ori Ite, Oba t’Ó wa l’ori obiri aye maa s’ola a Re lo
Aye ati orun nbo O, kos’elomiin t’o ye ko gba ijuba wa bi o se’Wo

Mo wari fun O o Olola
Imole t’O ntan s’inu ookun mi ogo f’ooko Re
L’eyin Re ko si o
Iwo nikan ni Oba
L’eyin Re ko si o
Iwo nikan ni Oba

Ad lib: Pelu iwariri lat’ogbun emi mi
Kos’elomiin Iwo ni, l’eyin Re Iwo naa ni
Olugbemiro, Olusaaanuumi, Olukemi, Olufunmilebun, Olugbemiro, Iwo nikan Olutimileyin

Mimo ni O mimo ni O oo mimo
Aye ati orun ns’oro ogo Re a n f’ise owo Re han, Iwo, mimo
Mo da ohun mi po mo gbogbo ise Re, emi, emi i mi ati eemi i mi a nyin O nigbagbogbo, Oba t’Ó
wa n’ipekun ola, ipekun ogo, ipekun agbara, ipekun ewa Iwo nikan ni Oluwa
Pipe naa l’O je Oluwa

Pipe ni O, pipe ni O o pipe
(Ta l’o le yo kuro ninu Re nigbat’a o tie mo)

Yiye ni O yiye ni O o yiye
(Iwo naa l’O wa fun’ra Re Iwo ni Oluwa, Odo Aguntan t’O joko s’ori Ite o yiye)

Tito ni O tito ni O o tito
(Tito ni O Eleda gbogbo iseda, Olutoju gbogbo eniyan, Olorun gbogbo eran ara, Eniti ngbo adura
odo Re l’a nwa Iwo ni)

Gigun ni O gigun ni O o gigun
(Oba t’O joko s’ori obiri aye, O fi aye so’le s’ori awon isan omi, aye ò le ri lailai ko le ri ise e Re ni,
gigun, o gun lailai)

Mo juba Re, Oba mimo, etc

Ad lib : Emi mi n juba Re nigbagbogbo
L’eyin Re kos’elomiin
I confess kos’elomiin
Olorun Eledumare t’O po n’ipa ati agbara Iwo ni o
Olorun awon’mo ogun Iwo nikan
Tani m ba juba bi o se’Wo
Olori egbegberun ogun awon angeli Iwo ni
Oluda aye kos’elomiin
Aseda gbogbo eniyan, Olorun gbogbo ede, Olorun gbogbo eya
Emi mi, eemi mi, ati emi naa
Imole t’o ntan ti ò le ku lailai
Olugbemiro, Olusaanuumi, Olugbamila, Oluyomi ninu okunkun
L’eyin Re ooo
Tani m ba sin bi o s’Enit’O gba mi la, Eniti mi ò ri sugbon ti mo r’ise Re ninu aye mi

Iwo nikan ni Oba

Ad lib: Olorun gbogbo araye Iwo nikan ni
Olutoju gbogbo eniyan Iwo nikan ni
Mo ki O ki O Iwo nikan ni Oba
Maa s’ola Re lo, maa s’ola Re lo kos’elomiin You Are The only One, You Are The only One Iwo
nikan, Holy, mimo mimo ni O Iwo ni Oba

Iwo nikan ni Oba.

TRANSLATION

Holy Are You
Holy Are You
Holy

Holy Are You
Holy Are You
Holy

Ad lib: God, The Almighty, greatest in strength and power
All creation says so, me too I say so, from the depth of my spirit

I pay homage, holy King
I bow for Him, King
After You, none other
Only You are King

I reverence You most worthy!
The Light shining in my darkness, glory to Your Name
After You, none other
Only You Are King

Added by

admin

SHARE

WRITE A TRANSLATION OR SUGGEST CORRECTION FOR THIS LYRICS

ADVERTISEMENT