LYRICS

Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn ìràwọ̀ kède ògo rẹ
Kíni o ha ṣe mí, tí n o nílè maa júbà Rẹ́ o e

Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn ìràwọ̀ kède ògo rẹ
Kíni o ha ṣe mí, tí n o nílè maa júbà Rẹ́ o e

Dídára ọ̀run ohún sọ t’ògo Rẹ o Ọlọ́run
Ẹwa Rẹ tó yí ayé ká ń sọ t’ògo Rẹ bó ti pọ̀ tó
Gbogbo ẹ̀da ẹranko àt’ewébẹ̀ ń yìn Ọ́ o
Iṣẹ́ ọwọ́ Rẹ gbogbo lo ń kéyìn le, wọ́n yín Ọ o Baba
(Ìbà rẹ ni gbogbo wọn ń jú)

Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn ìràwọ̀ kède ògo rẹ
Kíni o ha ṣe mí, tí n o nílè maa júbà Rẹ́ o e

Ọlá lowò láṣọ, ògo lo fi pa kádà ọ̀run
Ìka ẹsẹ̀ Rẹ o ń hàn l’órí àpáta
Ẹ̀sin Rẹ ń f’ògo yan l’órí àwọn òkun o Ọlọ́lá ńlá
Kíni o ha ṣe mí ti ń o jòkèlèyó
Tí n ò ní lè júbà Rẹ́ Ọba

Chorus: Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn ìràwọ̀ kède ògo rẹ
Kíni o ha ṣe mí, tí n o nílè maa júbà Rẹ́ o e

Interlude
Gbogbo eemí inú miii o ń yìn Ọ yàtọ̀ Ọlọrún mi
Ìwọ to mú mi la iná kọjá to fi mú mi gòkè
Kíni ń ba fi fún Ọ
Kíni mo tòsì nínu ore ọ̀fẹ́ ti mo rígbà lọ́dọ̀ Rẹ
O báyé mi dá májẹ̀mú láti nú’mọlẹ̀
Ọ̀rọ̀ ye ye oṣiṣẹ
Ọba t́i kì ń dalẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀
Ìwárìrì ni ń o fi júbà Rẹ̀ (Ìwárìrì ni ń o fi júbà Rẹ)

Chorus: Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ọ̀run òhun ayé kún fún ògo rẹ
Ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn ìràwọ̀ kède ògo rẹ
Kíni o ha ṣe mí, tí n o nílè maa júbà Rẹ́ o e (2x)

TRANSLATION

Heaven and earth are filled with your glory
Heaven and earth are filled with your glory
Tens of thousands of stars proclaim your glory
Why then, will I not be able to worship you?

Heaven and earth are filled with your glory
Heaven and earth are filled with your glory
Tens of thousands of stars proclaim your glory
Why then, will I not be able to worship you?

The beauty of heaven proclaim your glory O God of heaven
Your beauty that that fills the earth proclaims how much your glory is
All human, animals and plants praise you
All the work of your hands have joined to praise you o father.
(They are all worshipping you)

Heaven and earth are filled with your glory
Heaven and earth are filled with your glory
Tens of thousands of stars proclaim your glory
Why then, will I not be able to worship you?

You are clothed with wealth, you wear glory around your neck
Your toes shine on a rock
Your shadow dazzles on rich oceans
Why then, will I not be able to dance, will I not be able to worship you King?

Chorus: Heaven and Earth are filled with your glory
Heaven and earth are filled with your glory
Tens of thousands of stars proclaim your glory
Why then, will I not be able to worship you?

Interlude
All my breath praises you differently O my God of Heavens
You who made me pass through fire and lifted me up
What am I to give you?
What do I deserve in all the free gifts that I get from you?
He made a covenant with my life from the light
The word came to pass
The king that doesn’t betray his words
I tremble to worship you
(I tremble to worship you)

Chorus: Heaven and earth are filled with your glory
Heaven and earth are filled with your glory
Tens of thousands of stars proclaim your glory
Why then, will I not be able to worship you? (2x)

Added by

admin

SHARE

WRITE A TRANSLATION OR SUGGEST CORRECTION FOR THIS LYRICS

ADVERTISEMENT