LYRICS

Ask me who is Jesus
And I will tell you things he has done for me
Ask me why I love him
And I will tell you how much he loved me
When I’ve not met him at all
Òun ló wá mi rí nígbà ti mo rìnnà ṣáko
Òun ló wẹ̀ mí nínu ẹ̀jẹ̀ rẹ̀
Mosì mọ̀
Ìyebíye ni ìràpadà mi
Eeeeeeh

Tàlò da bí rẹ (tàlò dà bí rẹ oo)
L’áyé a’tọrùn (ooo kòsí o)
Kòsí o (ee)
Kòsí o (ẹ mà sí o)
Mí o rirí kò ma sí
Tàlò da bí rẹ (tàlò da bi rẹ ooo)
L’áyé a’tọ̀run (tàlò da bí Ọba mi òkè tó kú fún mi)
Kòsí o (mmm kòsí)

His name is Jesus
He’s unmoved, unchanged and undefeated
Tested and Trusted
He has done it for me and he will do more
Over and over again
Alágbàwí rere bí Jésù
Mi ò rirí
Òun ló fẹ́wa ní àfẹ́jù àt’àfẹtán
Olùṣọ́ àgùntàn rere (olùṣọ́ àgùntàn rere ni)

Tàlò da bi rẹ (aláfẹ́jù aláfẹ́tán)
L’áyé at’ọrùn (ẹni tó pọ̀ nípá àt’agbára)
Kòsí o (tí o fipá ẹ ṣe, tí o f’agbára ẹ̀ ṣe)
Kòsí o (to ń fẹ mí lọ fẹ mí bọ̀)
Tàlò dàbi rẹ (onífẹ̀ ràgbàdà e)
L’áyé at’ọ́rùn (onífẹ̀ tó mọ́lẹ̀ rokoso oo)
Kòsí o (ìmọ́lẹ̀ ìfẹ́ ìtàná ìfẹ́)
Kòsí o (Ọlọ́run ńlá)
(Tàlò dà bí rẹ oo)
Tàlò dà bí rẹ (kò mà sí o)
L’áyé at’ọ̀run (mi ò rirí, mi ò dẹ̀ leri, mo ti wa mi ò rí ọ)
Kòsí o
Kòsí o (kò ma sí o, e e, ẹ ba n wo nífẹ̀ bi ti Jésù)
Tàlò dà bí rẹ ( ẹ̀ ò le rí, ẹ̀ ò le rí)
L’áyé at’ọ̀run (bí bàbá bá fẹ́ràn ọmọ, a fọmọ sílẹ̀ láyé lọ)
Kòsí o (Jésù nìkan ni kì ń fi ni sílẹ̀ o)
Kòsí o (o ń báni rin ìrìn àjò gbogbo)

I call him my rock
Sure, he never fails
He’s my redeemer
He defends me oooo
Òun lo gbé mí ro nígbà ti mo yọ̀ subú
And he fights my battles all the way
Eeee

Tàlò dà bí rẹ (kòsí o)
L’áyé at’ọ̀run (kòsí o)
Kòsí o (ooo)
Kòsí o (ọ̀rẹ bí Jésù, there’s not a friend like Jesus, yes)
Tàlò dà bí rẹ (mo wa tó, mo wa tó)
Kòsí o (kòsí oooo)
Kòsí o (olùgbàlà tó dà bí rẹ)
Tàlò da bí rẹ (b’áyé wi, irọ́ ni wọ́n pa)
L’áyé at’ọ̀run (b’áyé sọ ọ̀tẹ̀ ni yóò gbẹ̀hìn rẹ̀)
Kòsí o (ìwọ nìkan l’olùgbani là e)
(kò ma sí)
Tàlò dà bí rẹ (e e mà sí)
L’áyé at’ọ̀run
Kòsí o (o o o o)
Kòsí o
There is no one, nobody like you,
Nobody like my Jesus, nobody like my saviour
Kòsí o

TRANSLATION


Added by

admin

SHARE

WRITE A TRANSLATION OR SUGGEST CORRECTION FOR THIS LYRICS

ADVERTISEMENT