LYRICS

Tìrẹ ni, tìrẹ ni, tirẹ ni, tìrẹ ni
Tìrẹ ni Olúwa
Mófi silẹ̀ fún Ọ o
Tìrẹ ni Olúwa
Ówúrọ, ọ̀sán mi, alẹ́ mi, tìrẹ ni…
Kíni n bá jẹ́ gba de rẹ oo
Gbogbo ayé mi d’ọwọ́ Rẹ o baba mi o
Tìrẹ ni o, tìrẹ ni o, tìrẹ ni ooo
Gbogbo ohun tí mo ní… ohun tí mo ni tìrẹ ni o
Gbogbo ohun tí mo ní tìrẹ ni o
Tìrẹ ni o, tìrẹ ni o. ìwọ ni mo fi fún l’áyé àti ọ̀run
Tìrẹ ni bàbá o
Olúwa tìrẹ ni o
Bàbá ìwọ lo ní maa gbògo lọọọ
Tìrẹ ni, tìrẹ ni, tìrẹ ni, tìrẹ ni, tìrẹ ni Olúwa
Àwọn kan l’áyé, wọn fògo fún ohun tí ó lẹ́nu tí kòle sọ̀rọ̀
Àwọn kan gbẹ́kẹ̀lé kẹ̀kẹ́ àti ohun ìjà olóró
Àwọn kan gbẹ́kẹ̀lé àwòrawọ̀ láyé wọn
Ìwọ tí èmi gbẹ́kẹ̀lé ni mo fi gbogbo ayé mi fún
Tìrẹ ni o, tìrẹ ni o, tìrẹ ni ooo
Gbogbo ohun tí mo ní… ohun tí mo ní tìrẹ ni o
Olùdásáyé mi ìwọ ni mo fògo fún
Tìrẹ ní o, tìrẹ màmà ni
Tìrẹ ni bàbá, Olúwa tìrẹ ni o

Interlude
Èmi ò le fògo ayé mi fún alágbára ayé
Èmi ò le fògo ayé mi fún ẹlẹ́bọ ayé
Kò sẹ́ni náà bàbá tólè bá ọ pín ògo rẹ
ohun gbogbo tí mojẹ́ ìwọ ni o
ohun gbogbo tí modé o, ìwọ ni o
Ìwọ ni ohun gbogbo tí mojẹ́ láyé o
Response: gba gbogbo ògo o
Call: gbá o
Response: gba gbogbo ọlá aa
Call: ọlá, ìwọ tó lògo
Response: gba gbogbgo ògo o
Call: gba gbogbo ẹ̀yẹ
Response: ìyin rẹ kòní tán lẹ́nu mi
Call: kòní tán an
Response: kòní tán ooo
Call: oṣé, o ṣé, oṣé, ẹlẹ́rù níyìn
Response: gba gbogbo ògo o
Call: oṣé
Response; gba gbogbo ọlá a
Call: ìwọ lo lọlá atẹ̀yẹ
Response: gba gbogbo ògo o
Call: orógojìgo olú ọ̀run
Response: ìyìn rẹ kòní tan lẹ́nu mi, bàbá o
Call: ìyìn rẹ kòní tán o

Interlude
Atóbájayé bàbá
Tìrẹ lójẹ́
Ọ̀ráńmọ níṣẹ́ fàyàtì, akọni ẹlẹ́rù
Ìwọ tó gbẹ̀mí jáde láti inú ère wá
O fàmí jókò larín àwọn ọmọ aládé
Ògo aye mí ỌlỌ́run àgbayé lóle gbà o
ÌwỌ lótó bẹẹ, o ju bẹ́ẹ̀ lọ
Tìrẹ ni o, tìrẹ ni o, tìrẹ ni ooo
Gbogbo ohun tí mo ní… ohun tí mo ní tìrẹ ni o
Gbogbo ohun tí mo ní láyé àtomi àtẹ̀jẹ̀ ara
Tìrẹ ni o, tìrẹ ni o. ìwọ ni mo fi fún l’áyé àti ọ̀run
Tìrẹ ni bàbá o, Olúwa tìrẹ ni o
Olódùmarè tí yóò bókùnkùn tìrẹ ni bàbá
Gba gbogbo ògo o
Gba gbogbo ọlá a (gbá o)
Gba gbogbo ògo ee (gbá o)
Ìyìn rẹ kòní tán lẹ́nu mi (kòní tán o)
O ṣeun, o ṣeun, oṣé ẹlẹ́rùniyìn
Gba gbogbo ògo o (Ọba àwọn ọba)
Gba gbogbo ọlá a (olórí ayé òhun ọ̀run)
Ìyìn rẹ kòní tán lẹ́nu mi
O ṣeun, o ṣeun, o ṣeun
Tìrẹ ni o, tìrẹ ni o, tìrẹ ni ooo
Gbogbo ohun tí mo ní, tí moní tìrẹ ni o
Ìwọ lóni mí láti irun orí dé èekáná esẹ̀
Tìrẹ ni o, tìrẹ ni o, ìwọ ni mo fifún láyé àtọrun
Tìrẹ ni bàbá o, Olúwa tìrẹ ni o
(Ọba tó lèní, àti ìgbà gbogbo)
Tìrẹ ni o, tìrẹ ni o o
Gbogbo ohun tí mo ní o, tí moní, tìrẹ ni o
Ohun tí mojẹ́, tí modà, tí mo mọ̀ láyé, ìwọ ni
Tìrẹ ni o, ìwọ ni mo fifún láyé àtọ̀run
Gbogbo ohun tí mo baba o, Olúwa tìrẹ ni o
Ọba tómọ ìbẹ̀rẹ̀ ayé mi

TRANSLATION

It belongs to you (4x)
It is yours Lord
I surrender it to you
It belongs to you Lord
My morning, afternoon, night, it belongs to you
What would I have been if not for you?
All my life is in your hands my father
It belongs to you (3x)
All I have, all I have belongs to you (3x)
It all belongs to you (2x)
I give it all to you in heaven and on earth
It is all yours father
Lord, it is yours
Father, it is yours continue taking all the Glory
It all belongs to you (4x) it all belongs to you Lord
Some people in the world give glory to things that do not have mouth that cannot talk
Some people rely on chariots and terrible weapons
Some people rely on astrologers in their life
You who I rely on, is who I give all my life to
It all belongs to you (3x)
All I have, all I have belongs to you
My keeper, it is you I give all the glory
It is yours, it belongs to you
It is yours father, Lord it is yours

Interlude
I cannot give the glory of my life to the powerful man on earth
I cannot give the glory of my life to the one that makes earthly sacrifices
There is no one father that can share in your glory
You are all I am
You are all I have reached
You are all I am on earth
Response: take all the glory
Call: take it
Response: take all the riches
Call: riches, you who own the glory
Response: take all the glory
Call: take all the adoration
Response: your praises will not cease from my mouth
Call: it won’t cease
Response: it won’t cease
Call: thank you (3x) the one with fearful honour
Response: take all the glory
Call: thank you
Response: take all the riches
Call: you own the wealth a0nd adoration
Response: take all the glory
Call: enormous God of heaven
Response: your praise will not cease from my mouth father
Call: your praise won’t cease

Interlude
Loving father
It is yours
You who sends a child on errand and stays with him, the brave man
You lifted me up from the miry clay
You made me sit among princes
The glory of my life belongs to God almighty
You are more than enough
It belongs to you (3x)
All I have, all I have belongs to you
All I have on earth, including my blood, sweat and body
Belongs to you (2x) I give all to you in heaven and on earth
It belongs to you father, it is all yours Lord
The creator of heaven and earth that blesses, it is yours father
Take all the glory
Take all the riches (take it)
Take all the glory (take it)
Your praises will not cease from my mouth (it won’t cease)
Thank you (2x) thanks to the one with fearful honour
Take all the glory (king of kings)
Take all the riches (God of heaven and earth)
Your praise will not cease from my mouth
Thank you (3x)
It all belongs to you (3x)
Everything I have, all I have belongs to you
You own me, from the strands of my hair to the nails on my toes
It all belongs to you (2x) I give all to you both in heaven and on earth
It belongs to you father, Lord it is yours
(The king who owns today and forever)
It all belongs to you (2x)
Everything I have, all I have belongs to you
All I have, all I have become, the heights I have reached on earth has been you
It belongs to you, I give you all on earth and in heaven
It belongs to you, I give you all on earth and even heaven
All I have reached father, Lord belongs to you
The king who knows the beginning of my life


Added by

admin

SHARE

WRITE A TRANSLATION OR SUGGEST CORRECTION FOR THIS LYRICS

ADVERTISEMENT